ASIIRI AWON OJO BUBURU TO WA NINU ODUN

 (ASIRI AWON OJO BUBURU) 


Awon ojo metadinladota ni ko dara rara larin odun kan gegebi o ti han lati ojo pipe awon baba nla wa, ti o sit un nhan be titi di isinsinyii, sugbon awon ologbon ni o nkiyesi si awon ojo wonyii ninu osun kookan larin odun.

Awon nkan wonyii ni awon ohun buburu ti ma nsaba sele ninu awon ojo wonyii;

1. Eniti aisan ba kolu ni okan ninu awon ojo wonyii, pelu agbara kaka ni eni na yio fi ri itoju.

2. Omo ti won ba bi ni okan ninu awon ojo wonyii nfe adura ati itoju gidi ki ailera ma bap o fun ati ki ojo re le pe lale.


3. Bi eniyan ban se igbeyewa ninu ikan ninu awon ojo wonyii, ija pelu iponju ma npo ninu tru idile bee.

4. Bi eniyan ba bere irin-ajo oju omi ninu ojo wonyi, a ma jasi pe aisan ni yio ba pada wa sile tabi ki jamba kan se eni naa.

5. Mase bere ile kiko rara ni nu okan awon ojo wonyii, be pelu mase dawo le ohun rere Kankan ninu ojo wonyii

6. Awon ojo meta kan wa ninu awon ojo wonyii ti won buru ju gbogbo ojo loo.: (1) APRIL !, ojo ti won bi Judasi Iskariot to se atona bi won se mu

Jesu Kristi Oluwa wa (2) AUGUST 1, ojo yii ni won le esu kuro ni orun, (3) DECEMBER 1, ojo yii ni Olorun pa Sodomu ati Gomara run, nitorina a ko gbodo dawole ohun Pataki Kankan ni ojo wonyii

Awon ojo na niwonyii:

January

1, 2, 6, 11, 17, & 18

February

8, 16, 17,

March

1, 3, 12, 13, 15

April

1, 3, 15, 17, 18

May

8, 10, 17, 30

June

1.7.10

July

1,5,6

August

1, 3, 17, 18, 20

September

1, 2, 17, 18, 30

October

15,17

November

1. 7.11

December

1. 7.11

Ranti ohun ti iwé isaiah 45 ese 7 wipe: "Mo da imole, mo da okunkun.mo se Alafia,mo da ibi. Emi Oluwa ni o se gbogbo wonyi".

 Yio dara pupo ti a ba le pa awon ojo wonyi mo dada pelu akiesii nkankan ma nko ni si iyonu,

Aye ko ni fi oro temi kogbon o. (Amin)

AOG OYEYEMI

SOGEM

Comments

Popular posts from this blog

ONLY ONE LIFE

THEIR JOURNEY IS YOUR RESCUE